Gbajugbaja apanilẹrin ati oṣere Nollywood, Princess ti bu ẹnu atẹ lu gbajugbaja oṣere, Idowu Philips ti gbogbo eniyan mọ si Mama Rainbow, lori ọrọ to sọ nipa Baba Ijesha. Ohun to da ija silẹ laarin ...
Oṣere ati adẹrinpoṣonu, Damilola Adekoya, ti ọpọ mọ si Princess ti kede pe oun n wa ọkọ, oun si ti ṣẹtan lati ni ololufẹ. Princess lo sọ ọrọ naa ninu fidio kan to fi lede loju opo Instagram rẹ nibi to ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results